News:

Create new topics and Join our discussions!

Main Menu

Ẹ káàbọ̀! Osunponmile Aduke!

Started by asobode, Oct 28, 2022, 04:12 PM

Previous topic - Next topic

asobode

Ẹ káàbọ̀! @Osunponmile Aduke!

Thank you for joining us!

Feel free to join our discussions or start a new one.

Introducing yourself is optional.

If you have any questions about our site you can post in the Help section or message @Omowale directly.

Osunponmile Aduke

Oruko mi ni osunponmile Aduke omo bibi ilu osun ni mi ni agbegbe osogbo,se kín wole

Atipo

Ẹ máa wọlé, Ẹ Káàbọ̀ yèyé wa, inú mi dùn pé ẹ darapọ̀ mọ́ wa. Orúkọ mi ni Ọlọ́ládé ṣùgbọ́n ẹ lè pè mí ní Àtìpó ọmọ ìlú Ìlárá-Mọ̀kín ní mi, tó súnmọ́ Àkúrẹ́, ṣùgbọ́n mò ń gbé láàjò. Ṣé Ọlọ́ṣun ni yín?

Osunponmile Aduke

Bẹẹni arugbá ajé inisha ni mi ni ipinle osun emi naa nio sile mọn ajoo lèmi naa wa

Omowale

~Manifest destiny from within~

Ayobamikale

Láti ọwọ́ Ayọ̀bámikalẹ́