News:

Create new topics and Join our discussions!

Main Menu

Typing in Yorùbá | Ìtẹ̀wé Lédè Yorùbá

Started by Ayobamikale, Nov 01, 2022, 04:29 AM

Previous topic - Next topic

Ayobamikale

Hey guys 👋🏿 I just wanted to share this quickly made guide for typing in Yorùbá that I made, so you guys can type in Yorùbá with tones and diacritics. In Yorùbá it is very important to show tones when writing words down as the lack of tones leads to a lack of understand written pieces. For those who are native speakers and want to learn how to write with tone, I suggest watching Adérónkẹ́ on YouTube. She just has a lot on her page that would be good for you guys to see!
--
Ẹ ǹlẹ́ ooo 👋🏿 Mo kàn fẹ́ pín atọ́nà tí mo tètè kọ fún ìtẹ̀wé lédè Yorùbá, nítorí náà ẹ lè kọ́ kọ èdè Yorùbá sílẹ̀ pẹ̀lú àmì ohùn. Lédè Yorùbá, ó ṣe pàtàkì púpọ̀ ká kọ ohun gbogbo pẹ̀lú àmì ohùn torí pé tá à lè ṣe é, ohun aláìṣeélóye la ó kọ. Fún ọmọ elédè Yorùbá lágbàáyé tó fẹ́ kọ́ kọ èdè Yorùbá pẹ̀lú àmì ohùn, ẹ wo Adérónkẹ́ lórí ẹ̀rọ YouTube. Ohun púpọ̀ tó wúlò nípa èdè, àṣà, àti ìṣe wa lòun ní lórí ìkànnì ti rẹ̀, kẹ́ lè wò!

Guide | Atọ́nà: Ètò Ìtẹ̀wé Lédè Yorùbá.pdf
Fídíò Adérónkẹ́'s Videos: https://www.youtube.com/c/yorubalessons/videos
Láti ọwọ́ Ayọ̀bámikalẹ́

Omowale

Thank you so much for providing this resource. This will be good for all of us. I have to catch up on her videos. May this thread serve as a valuable resource for others.. Àṣẹ.
~Manifest destiny from within~